SOKA: Mukaila fesi si oro ti Karanjogbon ilumoka Sunday Igboho so lori BBC yoruba

Alhaji Mukaila Lamidi fesi si oro ti Kanranjogbon ilumooka ni Sunday Adeyemo ti gbogbo eyan mo si Sunday igboho so Lori BBC Yoruba.
Alaga Park Management ti Ipinle Oyo Alh Lamidi Mukaila ti inogije re n je Auxiliary ti fesi si oro ti igboho so Lori ero ayelukara wipe ohun ko ye nipo Olori awon awako nipinle Oyo. MMK wipe aitetemole, ole Sunday igboho nmoloko. 
MMK ni didalowoko iwa ibaje eyi ti Sunday Adeyemo n wu ni garage ti o wa ni Soka ni o fa gbomisi omi o too eyi o sele ni Ojo Aje ti o koja. 
Ninu oro re o wipe se ti oju akata ba maa lewo, se enu Adiye Sunday Igboho lo ye ki a ti gbo. 
Leni to je wipe ojoojumo lo fin daamu awon olugbe Soka. Onile o gbodo fe kan ile, awon omo Ogun re yio ti tele sibe lati gbowo omo onile. Owo ipile ile, borehole, dekini kikun ati beebee lo.
O je ki o di mimo wipe lojo aje ti o koja ni okiki kan de ba own ni ofisi wipe Sunday igboho ti fi ibon le awon olokada ati olutaja Soka kuro. Logan ni own si lo sibe lati lo petu si aawo naa. Leyi ti o si ferege nigba ti o gburo wipe owun ti nbo lona. 
MMK wa ro gbogbo Omo Ipinle Oyo paapa julo olugbe inu Ibadan lati fi okan bale.
 Ijoba ti o n lo lowo o fe jagidijagan ati iwa yiyan omolakeji je. O wipe ohun ti setan lati fowosopo pelu ijoba Ipinle Oyo lati gbogun ti iwa ibaje ati iwa jagidijagan.

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Discover more from MouthpieceNGR

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading